Home Page
cover of ÌGBÀ NI GBOGBO NǸKÁN
ÌGBÀ NI GBOGBO NǸKÁN

ÌGBÀ NI GBOGBO NǸKÁN

Ilesanmi MoyinoluwaIlesanmi Moyinoluwa

0 followers

00:00-00:38

kò sí bí òkè kan ti lè ga tó gígùn ún dé téńté orí ẹ̀, bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ìṣísẹ̀ àkọ́kọ́ ìṣísẹ̀ kọ̀ọ̀kan tí a kò kà sí, ní ń darapọ̀ di ìgbésẹ̀ kan ńlá tí gbogbo ayé leè rí! nítorí náà ńkọ́? kò sígbà tó kéré kò sákòókò tí kò wúlò Ìṣẹ́jú aago kọ̀ọ̀kan Ló níṣẹ́ tó ń ṣe Má fàkókò ṣeré ó, Ọ̀rẹ́ wa.

Audio hosting, extended storage and much more

AI Mastering

Transcription

Kosibi yoke konti le e gato. Gigun deten te orie. Bere pelun ishi se akoko. Ishi se kokon se akokasi. Nin dara podi ibe se kanla. Sigu guwaye le e ri. Ni torina onko. Kosibi asokere. Kosa koko tiko ubulo. Ise dua goko okon. Loni se tonishi. Mafia koko shireu. Orewa.

Listen Next

Other Creators